-
2 Sámúẹ́lì 17:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Nígbà náà, Áhítófẹ́lì sọ fún Ábúsálómù pé: “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí n yan ẹgbẹ̀rún méjìlá (12,000) ọkùnrin, kí a sì gbéra láti lépa Dáfídì lálẹ́ òní.
-