-
Lúùkù 22:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 “Àmọ́ ẹ wò ó! ọwọ́ èmi àti ẹni tó máa dà mí jọ wà lórí tábìlì.+
-
-
Lúùkù 22:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Àmọ́ Jésù sọ fún un pé: “Júdásì, ṣé o fẹ́ fi ẹnu ko Ọmọ èèyàn lẹ́nu kí o lè dalẹ̀ rẹ̀ ni?”
-