ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 17:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Nígbà tí Áhítófẹ́lì rí i pé wọn ò tẹ̀ lé ìmọ̀ràn òun, ó de ohun tí wọ́n fi ń jókòó mọ́ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́,* ó sì lọ sí ilé rẹ̀ ní ìlú rẹ̀.+ Lẹ́yìn tó ti sọ ohun tí agbo ilé rẹ̀+ máa ṣe, ó pokùn so.*+ Torí náà, ó kú, wọ́n sì sin ín sí ibi tí wọ́n sin àwọn baba ńlá rẹ̀ sí.

  • 2 Sámúẹ́lì 18:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Jóábù bá sọ pé: “Mi ò ní fi àkókò mi ṣòfò lọ́dọ̀ rẹ mọ́!” Torí náà, ó mú aṣóró* mẹ́ta, ó sì fi wọ́n gún ọkàn Ábúsálómù ní àgúnyọ nígbà tí ó ṣì wà láàyè ní àárín igi ńlá náà.

  • Sáàmù 109:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Kí Jèhófà máa rántí gbogbo ohun tí wọ́n ṣe;

      Kí ó sì pa ìrántí wọn rẹ́ kúrò ní ayé.+

  • Mátíù 27:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Nígbà tí Júdásì, ẹni tó dà á, rí i pé wọ́n ti dá Jésù lẹ́bi, ẹ̀dùn ọkàn bá a, ó sì kó ọgbọ̀n (30) ẹyọ fàdákà náà pa dà wá fún àwọn olórí àlùfáà àti àwọn àgbààgbà,+

  • Mátíù 27:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Torí náà, ó da àwọn ẹyọ fàdákà náà sínú tẹ́ńpìlì, ó sì kúrò níbẹ̀. Ó wá lọ pokùn so.+

  • Ìṣe 1:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 “Ẹ̀yin èèyàn, ẹ̀yin ará, ó pọn dandan kí ìwé mímọ́ ṣẹ, èyí tí ẹ̀mí mímọ́ gba ẹnu Dáfídì sọ nípa Júdásì,+ ẹni tó ṣamọ̀nà àwọn tó wá mú Jésù.+

  • Ìṣe 1:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 (Ọkùnrin yìí fi owó iṣẹ́ ibi+ rẹ̀ ra ilẹ̀ kan, àmọ́, ó fi orí sọlẹ̀, ikùn rẹ̀ bẹ́,* gbogbo ìfun rẹ̀ sì tú síta.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́