1 Sámúẹ́lì 21:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Lọ́jọ́ yẹn, Dáfídì gbéra, ó tún bẹ̀rẹ̀ sí í sá lọ+ nítorí Sọ́ọ̀lù, níkẹyìn ó dé ọ̀dọ̀ Ákíṣì ọba Gátì.+
10 Lọ́jọ́ yẹn, Dáfídì gbéra, ó tún bẹ̀rẹ̀ sí í sá lọ+ nítorí Sọ́ọ̀lù, níkẹyìn ó dé ọ̀dọ̀ Ákíṣì ọba Gátì.+