-
Lúùkù 20:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Lẹ́yìn tí wọ́n ṣọ́ ọ dáadáa, wọ́n rán àwọn ọkùnrin tí wọ́n háyà ní bòókẹ́lẹ́ jáde pé kí wọ́n díbọ́n pé àwọn jẹ́ olódodo, kí wọ́n sì fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú un,+ kí wọ́n lè fà á lé ìjọba lọ́wọ́, kí wọ́n sì mú un lọ sọ́dọ̀ gómìnà.
-