Sáàmù 94:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Nígbà tí mo sọ pé: “Ẹsẹ̀ mi ń yọ̀,”Jèhófà, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ló ń gbé mi ró.+ Sáàmù 116:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 O ti gbà mí* lọ́wọ́ ikú,O gba ojú mi lọ́wọ́ omijé, o sì gba ẹsẹ̀ mi lọ́wọ́ ìkọ̀sẹ̀.+