Sáàmù 91:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Màá sọ fún Jèhófà pé: “Ìwọ ni ibi ààbò mi àti odi ààbò mi,+Ọlọ́run mi tí mo gbẹ́kẹ̀ lé.”+