Rúùtù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí Jèhófà san ẹ̀san ohun tí o ṣe fún ọ,+ kí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tí o wá ààbò wá sábẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀+ sì fún ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ èrè.” Sáàmù 17:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Dáàbò bò mí bí ọmọlójú rẹ;+Fi mí pa mọ́ sábẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ.+
12 Kí Jèhófà san ẹ̀san ohun tí o ṣe fún ọ,+ kí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ẹni tí o wá ààbò wá sábẹ́ ìyẹ́ apá rẹ̀+ sì fún ọ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ èrè.”