-
Sáàmù 57:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Kí a gbé ọ ga ju ọ̀run lọ, ìwọ Ọlọ́run;
Kí ògo rẹ wà lórí gbogbo ayé.+
-
-
Sáàmù 108:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Gbé ara rẹ ga ju ọ̀run lọ, ìwọ Ọlọ́run;
Kí ògo rẹ wà lórí gbogbo ayé.+
-