Róòmù 15:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 kí àwọn orílẹ̀-èdè sì lè yin Ọlọ́run lógo nítorí àánú rẹ̀.+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ìdí nìyẹn tí màá fi yìn ọ́ ní gbangba láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, tí màá sì fi orin yin orúkọ rẹ.”+
9 kí àwọn orílẹ̀-èdè sì lè yin Ọlọ́run lógo nítorí àánú rẹ̀.+ Gẹ́gẹ́ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ìdí nìyẹn tí màá fi yìn ọ́ ní gbangba láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, tí màá sì fi orin yin orúkọ rẹ.”+