Sáàmù 82:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Títí dìgbà wo ni ẹ ó máa fi àìṣòdodo dá ẹjọ́,+Tí ẹ ó sì máa ṣe ojúsàájú àwọn ẹni burúkú?+ (Sélà)