Àìsáyà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Sọ fún àwọn olódodo pé nǹkan máa lọ dáadáa fún wọn;Wọ́n máa jèrè iṣẹ́ ọwọ́ wọn.*+