1 Sámúẹ́lì 19:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Lẹ́yìn náà, Sọ́ọ̀lù rán àwọn òjíṣẹ́ sí ilé Dáfídì láti máa ṣọ́ ọ, kí wọ́n sì pa á ní àárọ̀ ọjọ́ kejì,+ ṣùgbọ́n Míkálì ìyàwó Dáfídì sọ fún un pé: “Tí o kò bá sá lọ* ní òru òní, wọ́n á pa ọ́ kó tó dọ̀la.”
11 Lẹ́yìn náà, Sọ́ọ̀lù rán àwọn òjíṣẹ́ sí ilé Dáfídì láti máa ṣọ́ ọ, kí wọ́n sì pa á ní àárọ̀ ọjọ́ kejì,+ ṣùgbọ́n Míkálì ìyàwó Dáfídì sọ fún un pé: “Tí o kò bá sá lọ* ní òru òní, wọ́n á pa ọ́ kó tó dọ̀la.”