Sáàmù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Nítorí ìnira àwọn tí ìyà ń jẹ,Nítorí ìkérora àwọn aláìní,+Màá dìde láti gbé ìgbésẹ̀,” ni Jèhófà wí. “Màá gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra wọn.”* Sáàmù 91:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ọlọ́run sọ pé: “Nítorí ó nífẹ̀ẹ́ mi,* màá gbà á sílẹ̀.+ Màá dáàbò bò ó torí pé ó mọ* orúkọ mi.+
5 “Nítorí ìnira àwọn tí ìyà ń jẹ,Nítorí ìkérora àwọn aláìní,+Màá dìde láti gbé ìgbésẹ̀,” ni Jèhófà wí. “Màá gbà wọ́n lọ́wọ́ àwọn tó kórìíra wọn.”*