Sáàmù 59:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Wọ́n ń wá ní ìrọ̀lẹ́ ìrọ̀lẹ́;+ Wọ́n ń kùn* bí ajá,+ wọ́n sì ń dọdẹ kiri ìlú.+