Òwe 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Orúkọ Jèhófà jẹ́ ilé gogoro tó lágbára.+ Olódodo sá wọ inú rẹ̀, ó sì rí ààbò.*+