Sáàmù 59:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run tó ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi yóò ràn mí lọ́wọ́;+Ọlọ́run yóò mú kí n rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.+
10 Ọlọ́run tó ń fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi yóò ràn mí lọ́wọ́;+Ọlọ́run yóò mú kí n rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.+