6 Ábúrámù rin ilẹ̀ náà já títí dé ibi tí Ṣékémù+ wà, nítòsí àwọn igi ńlá tó wà ní Mórè.+ Àwọn ọmọ Kénáánì wà ní ilẹ̀ náà nígbà yẹn. 7 Jèhófà wá fara han Ábúrámù, ó sì sọ pé: “Ọmọ rẹ+ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí.”+ Ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà, ẹni tó fara hàn án.