2 Sámúẹ́lì 10:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Kí a jẹ́ alágbára, kí a sì ní ìgboyà+ nítorí àwọn èèyàn wa àti àwọn ìlú Ọlọ́run wa, Jèhófà yóò sì ṣe ohun tó dára ní ojú rẹ̀.”+ Sáàmù 44:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Agbára rẹ la ó fi lé àwọn ọ̀tá wa pa dà;+Orúkọ rẹ la ó fi tẹ àwọn tó dìde sí wa rẹ́.+
12 Kí a jẹ́ alágbára, kí a sì ní ìgboyà+ nítorí àwọn èèyàn wa àti àwọn ìlú Ọlọ́run wa, Jèhófà yóò sì ṣe ohun tó dára ní ojú rẹ̀.”+