-
Sáàmù 5:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Fetí sí igbe ìrànlọ́wọ́ mi,
Ìwọ Ọba mi àti Ọlọ́run mi, torí pé ìwọ ni mò ń gbàdúrà sí.
-
-
Sáàmù 17:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Jèhófà, gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún ìdájọ́ òdodo;
Fiyè sí igbe mi fún ìrànlọ́wọ́;
Fetí sí àdúrà tí mo gbà láìṣẹ̀tàn.+
-
-
Sáàmù 28:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi nígbà tí mo bá ké pè ọ́ fún ìrànlọ́wọ́
Bí mo ṣe ń gbé ọwọ́ mi sókè sí yàrá inú lọ́hùn-ún ti ibi mímọ́ rẹ.+
-