Sáàmù 38:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àwọn tó ń wá ẹ̀mí* mi dẹ pańpẹ́ sílẹ̀;Àwọn tó fẹ́ ṣe mí léṣe ń sọ nípa ìparun;+Ẹ̀tàn ni wọ́n ń sọ lẹ́nu wúyẹ́wúyẹ́ láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.
12 Àwọn tó ń wá ẹ̀mí* mi dẹ pańpẹ́ sílẹ̀;Àwọn tó fẹ́ ṣe mí léṣe ń sọ nípa ìparun;+Ẹ̀tàn ni wọ́n ń sọ lẹ́nu wúyẹ́wúyẹ́ láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.