1 Sámúẹ́lì 1:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ni Hánà bá dáhùn pé: “Kò rí bẹ́ẹ̀, olúwa mi! Ìdààmú ńlá ló bá mi;* kì í ṣe pé mo mu wáìnì tàbí ọtí kankan, ohun tó wà lọ́kàn mi ni mò ń tú jáde níwájú Jèhófà.+
15 Ni Hánà bá dáhùn pé: “Kò rí bẹ́ẹ̀, olúwa mi! Ìdààmú ńlá ló bá mi;* kì í ṣe pé mo mu wáìnì tàbí ọtí kankan, ohun tó wà lọ́kàn mi ni mò ń tú jáde níwájú Jèhófà.+