Òwe 14:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ìbẹ̀rù Jèhófà máa ń fọkàn ẹni balẹ̀ pẹ̀sẹ̀,+Yóò sì jẹ́ ibi ààbò fún àwọn ọmọ rẹ̀.+