ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 9:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ọlọ́gbọ́n ni,* ó sì ní agbára gan-an.+

      Ta ló lè ta kò ó, tí kò ní fara pa?+

  • Náhúmù 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Jèhófà kì í tètè bínú,+ agbára rẹ̀ sì pọ̀,+

      Àmọ́, Jèhófà kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹni tí ìyà bá tọ́ sí.+

      Ọ̀nà rẹ̀ wà nínú ẹ̀fúùfù àti ìjì líle,

      Àwọsánmà sì ni eruku ẹsẹ̀ rẹ̀.+

  • Ìfihàn 19:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Lẹ́yìn èyí, mo gbọ́ ohun kan ní ọ̀run tó dún bí ohùn àwọn tó pọ̀ gan-an. Wọ́n sọ pé: “Ẹ yin Jáà!*+ Ti Ọlọ́run wa ni ìgbàlà àti ògo àti agbára,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́