1 Sámúẹ́lì 23:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Dáfídì ń gbé ní aginjù ní àwọn ibi tó ṣòroó dé, ní agbègbè olókè tó wà ní aginjù Sífù.+ Gbogbo ìgbà ni Sọ́ọ̀lù ń wá a kiri,+ àmọ́ Jèhófà kò fi lé e lọ́wọ́.
14 Dáfídì ń gbé ní aginjù ní àwọn ibi tó ṣòroó dé, ní agbègbè olókè tó wà ní aginjù Sífù.+ Gbogbo ìgbà ni Sọ́ọ̀lù ń wá a kiri,+ àmọ́ Jèhófà kò fi lé e lọ́wọ́.