Àìsáyà 26:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ní òru, gbogbo ọkàn* mi wà lọ́dọ̀ rẹ,Àní, ẹ̀mí mi ń wá ọ ṣáá;+Torí tí àwọn ìdájọ́ bá ti ọ̀dọ̀ rẹ wá sí ayé,Àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà máa kọ́ òdodo.+
9 Ní òru, gbogbo ọkàn* mi wà lọ́dọ̀ rẹ,Àní, ẹ̀mí mi ń wá ọ ṣáá;+Torí tí àwọn ìdájọ́ bá ti ọ̀dọ̀ rẹ wá sí ayé,Àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà máa kọ́ òdodo.+