Sáàmù 42:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mò* ń wá Ọlọ́run, Ọlọ́run alààyè, bí ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ ṣe ń wá omi.+ Ìgbà wo ni kí n wá, kí n sì fara hàn níwájú Ọlọ́run?+
2 Mò* ń wá Ọlọ́run, Ọlọ́run alààyè, bí ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ ṣe ń wá omi.+ Ìgbà wo ni kí n wá, kí n sì fara hàn níwájú Ọlọ́run?+