1 Sámúẹ́lì 17:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Dáfídì wá fi kún un pé: “Jèhófà tó gbà mí lọ́wọ́* kìnnìún àti bíárì náà, ló máa gbà mí lọ́wọ́ Filísínì yìí.”+ Sọ́ọ̀lù bá sọ fún Dáfídì pé: “Máa lọ, kí Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ.”
37 Dáfídì wá fi kún un pé: “Jèhófà tó gbà mí lọ́wọ́* kìnnìún àti bíárì náà, ló máa gbà mí lọ́wọ́ Filísínì yìí.”+ Sọ́ọ̀lù bá sọ fún Dáfídì pé: “Máa lọ, kí Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ.”