Sáàmù 7:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọlọ́run jẹ́ Onídàájọ́ òdodo,+Ọlọ́run sì ń kéde ìdájọ́ rẹ̀* lójoojúmọ́. 12 Bí ẹnikẹ́ni kò bá ronú pìwà dà,+ Á pọ́n idà rẹ̀;+Á tẹ ọrun rẹ̀, á sì mú kó wà ní sẹpẹ́.+
11 Ọlọ́run jẹ́ Onídàájọ́ òdodo,+Ọlọ́run sì ń kéde ìdájọ́ rẹ̀* lójoojúmọ́. 12 Bí ẹnikẹ́ni kò bá ronú pìwà dà,+ Á pọ́n idà rẹ̀;+Á tẹ ọrun rẹ̀, á sì mú kó wà ní sẹpẹ́.+