-
Òwe 26:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ẹni tó gbẹ́ kòtò yóò já sínú rẹ̀,
Ẹni tó bá sì yí òkúta kúrò, òkúta náà yóò pa dà sórí rẹ̀.+
-
-
Àìsáyà 3:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ẹni burúkú gbé!
Àjálù máa dé bá a,
Torí ohun tó fi ọwọ́ ara rẹ̀ ṣe ni wọ́n máa ṣe fún un!
-