Sáàmù 116:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Màá san àwọn ẹ̀jẹ́ mi fún Jèhófà+Níwájú gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀,+ Oníwàásù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+
18 Màá san àwọn ẹ̀jẹ́ mi fún Jèhófà+Níwájú gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀,+ Oníwàásù 5:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+
4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+