Sáàmù 36:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ mà ṣeyebíye o, Ọlọ́run!+ Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ ni àwọn ọmọ èèyàn fi ṣe ibi ààbò.+ 8 Wọ́n ń mu àwọn ohun tó dára jù lọ ní* ilé rẹ ní àmutẹ́rùn,+O sì mú kí wọ́n máa mu nínú adùn rẹ tó ń ṣàn bí odò.+
7 Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ mà ṣeyebíye o, Ọlọ́run!+ Abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ ni àwọn ọmọ èèyàn fi ṣe ibi ààbò.+ 8 Wọ́n ń mu àwọn ohun tó dára jù lọ ní* ilé rẹ ní àmutẹ́rùn,+O sì mú kí wọ́n máa mu nínú adùn rẹ tó ń ṣàn bí odò.+