-
Àìsáyà 57:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 “Àmọ́ àwọn ẹni burúkú dà bí òkun tó ń ru, tí kò lè rọ̀ wọ̀ọ̀,
Omi rẹ̀ sì ń ta koríko inú òkun àti ẹrẹ̀ sókè.