Àìsáyà 55:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ máa fi ayọ̀ jáde lọ,+A sì máa mú yín pa dà ní àlàáfíà.+ Àwọn òkè ńlá àtàwọn òkè kéékèèké máa fi igbe ayọ̀ túra ká níwájú yín,+Gbogbo àwọn igi inú igbó sì máa pàtẹ́wọ́.+
12 Ẹ máa fi ayọ̀ jáde lọ,+A sì máa mú yín pa dà ní àlàáfíà.+ Àwọn òkè ńlá àtàwọn òkè kéékèèké máa fi igbe ayọ̀ túra ká níwájú yín,+Gbogbo àwọn igi inú igbó sì máa pàtẹ́wọ́.+