Àìsáyà 37:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Torí bí inú rẹ ṣe ń ru sí mi+ àti bí o ṣe ń ké ramúramù ti dé etí mi.+ Torí náà, màá fi ìwọ̀ mi kọ́ imú rẹ, màá fi ìjánu+ mi sáàárín ètè rẹ,Ọ̀nà tí o gbà wá ni màá sì mú ọ gbà pa dà.”
29 Torí bí inú rẹ ṣe ń ru sí mi+ àti bí o ṣe ń ké ramúramù ti dé etí mi.+ Torí náà, màá fi ìwọ̀ mi kọ́ imú rẹ, màá fi ìjánu+ mi sáàárín ètè rẹ,Ọ̀nà tí o gbà wá ni màá sì mú ọ gbà pa dà.”