Sáàmù 56:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọlọ́run, ẹ̀jẹ́ tí mo jẹ́ fún ọ dè mí;+Màá rú ẹbọ ọpẹ́ sí ọ.+ Sáàmù 116:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Màá san àwọn ẹ̀jẹ́ mi fún JèhófàNíwájú gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀.+ Oníwàásù 5:4, 5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+ 5 Ó sàn kí o má ṣe jẹ́jẹ̀ẹ́ ju pé kí o jẹ́jẹ̀ẹ́, kí o má sì san án.+
4 Nígbàkigbà tí o bá jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún Ọlọ́run, má fi falẹ̀, san án,+ nítorí inú rẹ̀ kì í dùn sí àwọn òmùgọ̀.+ Ohun tí o jẹ́jẹ̀ẹ́, san án.+ 5 Ó sàn kí o má ṣe jẹ́jẹ̀ẹ́ ju pé kí o jẹ́jẹ̀ẹ́, kí o má sì san án.+