Sáàmù 34:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Aláìní yìí pe Jèhófà, ó sì gbọ́. Ó gbà á nínú gbogbo wàhálà rẹ̀.+ Sáàmù 65:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ìwọ Olùgbọ́ àdúrà, ọ̀dọ̀ rẹ ni onírúurú èèyàn* yóò wá.+ Sáàmù 116:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 116 Mo nífẹ̀ẹ́ JèhófàNítorí ó ń gbọ́* ohùn mi, ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́.+ 1 Jòhánù 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 a sì ń rí ohunkóhun tí a bá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ gbà,+ torí à ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, a sì ń ṣe àwọn ohun tó dáa lójú rẹ̀.
22 a sì ń rí ohunkóhun tí a bá béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ gbà,+ torí à ń pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, a sì ń ṣe àwọn ohun tó dáa lójú rẹ̀.