Náhúmù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+ Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+ Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀.
6 Ta ló lè dúró nígbà tó bá ń bínú?+ Ta ló sì lè fara da ooru ìbínú rẹ̀?+ Yóò tú ìbínú rẹ̀ jáde bí iná,Àwọn àpáta á sì fọ́ sí wẹ́wẹ́ nítorí rẹ̀.