Àìsáyà 12:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ní ọjọ́ yẹn, ẹ máa sọ pé: “Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, ẹ ké pe orúkọ rẹ̀,Ẹ jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ àwọn ohun tí ó ṣe!+ Ẹ kéde pé a ti gbé orúkọ rẹ̀ ga.+
4 Ní ọjọ́ yẹn, ẹ máa sọ pé: “Ẹ fi ọpẹ́ fún Jèhófà, ẹ ké pe orúkọ rẹ̀,Ẹ jẹ́ kí àwọn èèyàn mọ àwọn ohun tí ó ṣe!+ Ẹ kéde pé a ti gbé orúkọ rẹ̀ ga.+