-
Sáàmù 7:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Wàhálà tó dá sílẹ̀ á pa dà sí orí òun fúnra rẹ̀;+
Ìwà ipá rẹ̀ á sì já lé àtàrí rẹ̀.
-
-
Sáàmù 37:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Má banú jẹ́ nítorí ẹni
Tó gbèrò ibi, tó sì mú un ṣẹ.+
-
-
Òwe 5:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àwọn àṣìṣe ẹni burúkú ló ń dẹkùn mú un,
Àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ á sì wé mọ́ ọn bí okùn.+
-
-
Òwe 26:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ẹni tó gbẹ́ kòtò yóò já sínú rẹ̀,
Ẹni tó bá sì yí òkúta kúrò, òkúta náà yóò pa dà sórí rẹ̀.+
-