-
Jóṣúà 10:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ni àwọn ọba Ámórì+ márààrún bá kóra jọ pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun wọn, ìyẹn ọba Jerúsálẹ́mù, ọba Hébúrónì, ọba Jámútì, ọba Lákíṣì àti ọba Ẹ́gílónì, wọ́n sì lọ pàgọ́ ti Gíbíónì láti bá a jà.
-
-
Jóṣúà 10:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Jèhófà da àárín wọn rú níwájú Ísírẹ́lì,+ wọ́n sì pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ ní Gíbíónì, wọ́n lé wọn gba ọ̀nà tí wọ́n ń gbà gòkè lọ sí Bẹti-hórónì, wọ́n sì ń pa wọ́n títí lọ dé Ásékà àti Mákédà.
-