Nọ́ńbà 21:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà, wọ́n sì lọ gba Ọ̀nà Báṣánì. Ógù+ ọba Báṣánì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ sì jáde wá gbéjà kò wọ́n ní Édíréì.+ Diutarónómì 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ìgbà yẹn la gba ilẹ̀ ọba àwọn Ámórì méjèèjì + tí wọ́n wà ní agbègbè Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì títí dé Òkè Hámónì+ Diutarónómì 3:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 gbogbo ìlú tó wà lórí ilẹ̀ tó tẹ́jú,* gbogbo Gílíádì àti gbogbo Báṣánì títí dé Sálékà àti Édíréì,+ àwọn ìlú tó jẹ́ ti ilẹ̀ ọba Ógù ní Báṣánì.
33 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà, wọ́n sì lọ gba Ọ̀nà Báṣánì. Ógù+ ọba Báṣánì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ sì jáde wá gbéjà kò wọ́n ní Édíréì.+
8 “Ìgbà yẹn la gba ilẹ̀ ọba àwọn Ámórì méjèèjì + tí wọ́n wà ní agbègbè Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì títí dé Òkè Hámónì+
10 gbogbo ìlú tó wà lórí ilẹ̀ tó tẹ́jú,* gbogbo Gílíádì àti gbogbo Báṣánì títí dé Sálékà àti Édíréì,+ àwọn ìlú tó jẹ́ ti ilẹ̀ ọba Ógù ní Báṣánì.