-
Ẹ́kísódù 19:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Mósè wá sọ fún Jèhófà pé: “Àwọn èèyàn náà ò lè wá sórí Òkè Sínáì, torí o ti kìlọ̀ fún wa tẹ́lẹ̀ pé, ‘Pa ààlà yí òkè náà ká, kí o sì yà á sí mímọ́.’”+
-
-
Diutarónómì 33:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ó sọ pé:
“Jèhófà wá láti Sínáì,+
Ó sì tàn sórí wọn láti Séírì.
-