ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 15:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Ọ̀tá sọ pé: ‘Màá lépa wọn! Màá lé wọn bá!

      Màá pín ẹrù ogun wọn títí yóò fi tẹ́ mi* lọ́rùn!

      Màá fa idà mi yọ! Ọwọ́ mi yóò ṣẹ́gun wọn!’+

  • Hósíà 12:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Éfúrémù ń sọ pé, ‘Ní tòótọ́, mo ti di ọlọ́rọ̀;+

      Mo ti ní ọrọ̀.+

      Nínú gbogbo làálàá mi, wọn ò ní rí àìtọ́ tàbí ẹ̀ṣẹ̀ kankan.’

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́