Éfésù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí ó sọ pé: “Nígbà tó gòkè lọ sí ibi gíga, ó kó àwọn èèyàn lẹ́rú; ó fúnni ní àwọn ẹ̀bùn tí ó jẹ́ èèyàn.”+ Éfésù 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó fúnni ní àwọn kan gẹ́gẹ́ bí àpọ́sítélì,+ àwọn kan gẹ́gẹ́ bíi wòlíì,+ àwọn kan gẹ́gẹ́ bí ajíhìnrere,*+ àwọn kan gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́ àgùntàn àti olùkọ́,+
8 Torí ó sọ pé: “Nígbà tó gòkè lọ sí ibi gíga, ó kó àwọn èèyàn lẹ́rú; ó fúnni ní àwọn ẹ̀bùn tí ó jẹ́ èèyàn.”+
11 Ó fúnni ní àwọn kan gẹ́gẹ́ bí àpọ́sítélì,+ àwọn kan gẹ́gẹ́ bíi wòlíì,+ àwọn kan gẹ́gẹ́ bí ajíhìnrere,*+ àwọn kan gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́ àgùntàn àti olùkọ́,+