-
Diutarónómì 7:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 “Ó dájú pé díẹ̀díẹ̀ ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa lé àwọn orílẹ̀-èdè yìí kúrò níwájú rẹ.+ Kò ní jẹ́ kí o pa wọ́n run kíákíá, kí àwọn ẹranko búburú má bàa pọ̀ níbẹ̀ kí wọ́n sì ṣe yín lọ́ṣẹ́.
-