Nọ́ńbà 21:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà, wọ́n sì lọ gba Ọ̀nà Báṣánì. Ógù+ ọba Báṣánì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ sì jáde wá gbéjà kò wọ́n ní Édíréì.+
33 Lẹ́yìn náà, wọ́n pa dà, wọ́n sì lọ gba Ọ̀nà Báṣánì. Ógù+ ọba Báṣánì àti gbogbo àwọn èèyàn rẹ̀ sì jáde wá gbéjà kò wọ́n ní Édíréì.+