Sáàmù 58:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Olódodo yóò máa yọ̀ nítorí pé ó ti rí ẹ̀san;+Ẹ̀jẹ̀ ẹni burúkú yóò rin ẹsẹ̀ rẹ̀ gbingbin.+