Àìsáyà 45:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Èrè* Íjíbítì àti ọjà* Etiópíà àtàwọn Sábéà, àwọn tó ga,Máa wá bá ọ, wọ́n á sì di tìrẹ. Wọ́n á máa rìn lẹ́yìn rẹ, pẹ̀lú ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ tí wọ́n fi dè wọ́n,Wọ́n á wá bá ọ, wọ́n á sì tẹrí ba fún ọ.+ Wọ́n á gbàdúrà, wọ́n á sọ fún ọ pé, ‘Ó dájú pé Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ,+Kò sì sí ẹlòmíì; kò sí Ọlọ́run míì.’” Àìsáyà 60:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní àkókò yẹn, o máa rí i, o sì máa tàn yinrin,+Ọkàn rẹ máa lù kìkì, ó sì máa kún rẹ́rẹ́,Torí pé a máa darí ọrọ̀ òkun sọ́dọ̀ rẹ;Àwọn ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè máa wá sọ́dọ̀ rẹ.+
14 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Èrè* Íjíbítì àti ọjà* Etiópíà àtàwọn Sábéà, àwọn tó ga,Máa wá bá ọ, wọ́n á sì di tìrẹ. Wọ́n á máa rìn lẹ́yìn rẹ, pẹ̀lú ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ tí wọ́n fi dè wọ́n,Wọ́n á wá bá ọ, wọ́n á sì tẹrí ba fún ọ.+ Wọ́n á gbàdúrà, wọ́n á sọ fún ọ pé, ‘Ó dájú pé Ọlọ́run wà pẹ̀lú rẹ,+Kò sì sí ẹlòmíì; kò sí Ọlọ́run míì.’”
5 Ní àkókò yẹn, o máa rí i, o sì máa tàn yinrin,+Ọkàn rẹ máa lù kìkì, ó sì máa kún rẹ́rẹ́,Torí pé a máa darí ọrọ̀ òkun sọ́dọ̀ rẹ;Àwọn ohun àmúṣọrọ̀ àwọn orílẹ̀-èdè máa wá sọ́dọ̀ rẹ.+