-
Sáàmù 144:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Na ọwọ́ rẹ jáde látòkè;
Dá mi sílẹ̀, kí o sì gbà mí lọ́wọ́ omi tó ń ru gùdù,
-
Ìdárò 3:54Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
54 Omi ti ṣàn bò mí lórí, mo sì sọ pé: “Tèmi ti tán!”
-
-
Jónà 2:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Koríko inú omi wé mọ́ mi lórí.
-
-
-